12 Bí ìfẹ́ láti mú ọrẹ wá bá wà, Ọlọrun gba ohun tí eniyan bá mú wá. Ọlọrun kò bèèrè ohun tí eniyan kò ní.
Ka pipe ipin Kọrinti Keji 8
Wo Kọrinti Keji 8:12 ni o tọ