Kọrinti Keji 9:12 BM

12 Nítorí kì í ṣe àìní àwọn onigbagbọ nìkan ni iṣẹ́ ìsìn yìí yóo pèsè fún, ṣugbọn yóo mú kí ọpọlọpọ eniyan máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 9

Wo Kọrinti Keji 9:12 ni o tọ