Kọrinti Keji 9:4 BM

4 Nítorí bí àwọn ará Masedonia bá bá mi wá sọ́dọ̀ yín, tí wọ́n wá rí i pé ẹ kò tíì múra sílẹ̀, ìtìjú ni yóo jẹ́ fún wa, kí á má wá sọ tiyín, nígbà tí a ti fi ọkàn tan yín lórí ọ̀rọ̀ yìí.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 9

Wo Kọrinti Keji 9:4 ni o tọ