Kọrinti Keji 9:8 BM

8 Ọlọrun lè fun yín ní oríṣìíríṣìí ẹ̀bùn, tí ẹ óo fi ní ànító ninu ohun gbogbo nígbà gbogbo. Ẹ óo sì tún ní tí yóo ṣẹ́kù fún ohun rere gbogbo.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 9

Wo Kọrinti Keji 9:8 ni o tọ