A. Oni 1:21 YCE

21 Awọn ọmọ Benjamini kò si lé awọn Jebusi ti ngbé Jerusalemu jade; ṣugbọn awọn Jebusi mbá awọn ọmọ Benjamini gbé ni Jerusalemu titi di oni.

Ka pipe ipin A. Oni 1

Wo A. Oni 1:21 ni o tọ