A. Oni 6:2 YCE

2 Ọwọ́ Midiani si le si Israeli: ati nitori Midiani awọn ọmọ Israeli wà ihò wọnni fun ara wọn, ti o wà ninu òke, ati ninu ọgbun, ati ni ibi-agbara wọnni.

Ka pipe ipin A. Oni 6

Wo A. Oni 6:2 ni o tọ