A. Oni 6:3 YCE

3 O si ṣe, bi Israeli ba gbìn irugbìn, awọn Midiani a si gòke wá, ati awọn Amaleki, ati awọn ọmọ ìha ìla-õrùn; nwọn a si gòke tọ̀ wọn wá;

Ka pipe ipin A. Oni 6

Wo A. Oni 6:3 ni o tọ