Esr 3:1 YCE

1 NIGBATI oṣu keje si pé, ti awọn ọmọ Israeli si wà ninu ilu wọnni, awọn enia na ko ara wọn jọ pọ̀ bi ẹnikan si Jerusalemu.

Ka pipe ipin Esr 3

Wo Esr 3:1 ni o tọ