Esr 4:19 YCE

19 Mo si paṣẹ, a si ti wá, a si ri pe, lati atijọ wá, ilu yi a ti ma ṣọ̀tẹ si awọn ọba, ati pe irukerudo ati ọ̀tẹ li a ti nṣe ninu rẹ̀.

Ka pipe ipin Esr 4

Wo Esr 4:19 ni o tọ