3 Nigbana ni ọba bi i pe, kini iwọ nfẹ́, Esteri ayaba? ati kini ẹ̀bẹ rẹ̀? ani de idajì ijọba li a o si fi fun ọ.
Ka pipe ipin Est 5
Wo Est 5:3 ni o tọ