2. Sam 5:9 YCE

9 Dafidi si joko ni ile awọn ọmọ-ogun ti o ni odi, a si npè e ni ilu Dafidi. Dafidi mọ ògiri yi i ka lati Millo wá, o si kọ ile ninu rẹ̀.

Ka pipe ipin 2. Sam 5

Wo 2. Sam 5:9 ni o tọ