19 Angẹli na si tẹ̀ doje rẹ̀ bọ̀ ilẹ aiye, o si ké ajara ilẹ aiye, o si kó o lọ sinu ifúnti, ifúnti nla ibinu Ọlọrun.
Ka pipe ipin Ifi 14
Wo Ifi 14:19 ni o tọ