3 Ègún kì yio si si mọ́: itẹ́ Ọlọrun ati ti Ọdọ-Agutan ni yio si mã wà nibẹ̀; awọn iranṣẹ rẹ̀ yio si ma sìn i:
Ka pipe ipin Ifi 22
Wo Ifi 22:3 ni o tọ