Ifi 6:14 YCE

14 A si ká ọ̀run kuro bi iwe ti a ká; ati olukuluku oke ati erekuṣu li a si ṣí kuro ni ipò wọn.

Ka pipe ipin Ifi 6

Wo Ifi 6:14 ni o tọ