Ifi 6:15 YCE

15 Awọn ọba aiye ati awọn ọlọlá ati awọn olori ogun, ati awọn ọlọrọ̀ ati awọn alagbara, ati olukuluku ẹrú, ati olukuluku omnira, si fi ara wọn pamọ́ ninu ihò-ilẹ, ati ninu àpata ori òke:

Ka pipe ipin Ifi 6

Wo Ifi 6:15 ni o tọ