Ifi 6:16 YCE

16 Nwọn si nwi fun awọn òke ati awọn àpata na pe, Ẹ wólu wa, ki ẹ si fi wa pamọ́ kuro loju ẹniti o joko lori itẹ́, ati kuro ninu ibinu Ọdọ-Agutan na:

Ka pipe ipin Ifi 6

Wo Ifi 6:16 ni o tọ