16 Ki a ba le wasu ihinrere ani ni ẹkùn ti mbẹ niwaju nyin, ki a má si ṣogo ninu ãlà ẹlomiran nipa ohun ti o wà li arọwọto.
Ka pipe ipin 2. Kor 10
Wo 2. Kor 10:16 ni o tọ