2. Kor 11:12 YCE

12 Ṣugbọn ohun ti mo nṣe li emi ó si mã ṣe, ki emi ki o le mu igberaga kuro lọwọ awọn ti gberaga pe ninu ohun ti nwọn nṣogo, ki a le ri wọn gẹgẹ bi awa.

Ka pipe ipin 2. Kor 11

Wo 2. Kor 11:12 ni o tọ