2. Kor 11:7 YCE

7 Tabi ẹ̀ṣẹ ni mo dá ti emi nrẹ̀ ara mi silẹ ki a le gbé nyin ga, nitoriti mo ti wasu ihinrere Ọlọrun fun nyin lọfẹ?

Ka pipe ipin 2. Kor 11

Wo 2. Kor 11:7 ni o tọ