2. Kor 12:18 YCE

18 Mo bẹ̀ Titu, mo si rán arakunrin kan pẹlu rẹ̀; Titu ha rẹ́ nyin jẹ bi? nipa ẹmí kanna kọ́ awa rìn bi? ọ̀na kanna kọ́ awa tọ̀ bi?

Ka pipe ipin 2. Kor 12

Wo 2. Kor 12:18 ni o tọ