2. Kor 3:18 YCE

18 Ṣugbọn gbogbo wa nwò ogo Oluwa laisi iboju bi ẹnipe ninu awojiji, a si npawada si aworan kanna lati ogo de ogo, ani bi lati ọdọ Oluwa ti iṣe Ẹmí.

Ka pipe ipin 2. Kor 3

Wo 2. Kor 3:18 ni o tọ