2. Kor 5:15 YCE

15 O si ti kú fun gbogbo wọn, pe ki awọn ti o wà lãye ki o má si ṣe wà lãye fun ara wọn mọ́, bikoṣe fun ẹniti o kú nitori wọn, ti o si ti jinde.

Ka pipe ipin 2. Kor 5

Wo 2. Kor 5:15 ni o tọ