17 Nitorina ẹ jade kuro larin wọn, ki ẹ si yà ara nyin si ọ̀tọ, li Oluwa wi, ki ẹ máṣe fi ọwọ́ kàn ohun aimọ́; emi o si gbà nyin.
Ka pipe ipin 2. Kor 6
Wo 2. Kor 6:17 ni o tọ