Joh 10:32 YCE

32 Jesu da wọn lohùn pe, Ọpọlọpọ iṣẹ rere ni mo fi hàn nyin lati ọdọ Baba mi wá; nitori ewo ninu iṣẹ wọnni li ẹnyin ṣe sọ mi li okuta?

Ka pipe ipin Joh 10

Wo Joh 10:32 ni o tọ