Joh 10:33 YCE

33 Awọn Ju si da a lohùn, wipe, Awa kò sọ ọ li okuta nitori iṣẹ rere, ṣugbọn nitori ọrọ-odi: ati nitori iwọ ti iṣe enia nfi ara rẹ ṣe Ọlọrun.

Ka pipe ipin Joh 10

Wo Joh 10:33 ni o tọ