Joh 15:10 YCE

10 Bi ẹnyin ba pa ofin mi mọ́, ẹ o duro ninu ifẹ mi; gẹgẹ bi emi ti pa ofin Baba mi mọ́, ti mo si duro ninu ifẹ rẹ̀.

Ka pipe ipin Joh 15

Wo Joh 15:10 ni o tọ