Joh 15:11 YCE

11 Nkan wọnyi ni mo ti sọ fun nyin, ki ayọ̀ mi ki o le wà ninu nyin, ati ki ayọ̀ nyin ki o le kún.

Ka pipe ipin Joh 15

Wo Joh 15:11 ni o tọ