Luk 11:11 YCE

11 Tani iṣe baba ninu nyin ti ọmọ rẹ̀ yio bère akara lọdọ rẹ̀, ti o jẹ fun u li okuta? tabi bi o bère ẹja, ti o jẹ fun u li ejò dipo ẹja?

Ka pipe ipin Luk 11

Wo Luk 11:11 ni o tọ