Luk 11:15 YCE

15 Ṣugbọn awọn ẹlomiran ninu wọn wipe, Nipa Beelsebubu olori awọn ẹmi èṣu li o fi nlé awọn ẹmi èṣu jade.

Ka pipe ipin Luk 11

Wo Luk 11:15 ni o tọ