Luk 11:27 YCE

27 O si ṣe, bi o ti nsọ nkan wọnyi, obinrin kan nahùn ninu ijọ, o si wi fun u pe, Ibukun ni fun inu ti o bí ọ, ati ọmú ti iwọ mu.

Ka pipe ipin Luk 11

Wo Luk 11:27 ni o tọ