Luk 11:34 YCE

34 Oju ni imọlẹ ara: bi oju rẹ ba mọ́, gbogbo ara rẹ a mọlẹ; ṣugbọn bi oju rẹ ba buru, ara rẹ pẹlu a kun fun òkunkun.

Ka pipe ipin Luk 11

Wo Luk 11:34 ni o tọ