Luk 12:20 YCE

20 Ṣugbọn Ọlọrun wi fun u pe, Iwọ aṣiwere, li oru yi li a o bère ẹmi rẹ lọwọ rẹ: njẹ titani nkan wọnni yio ha ṣe, ti iwọ ti pèse silẹ?

Ka pipe ipin Luk 12

Wo Luk 12:20 ni o tọ