Luk 12:30 YCE

30 Nitori gbogbo nkan wọnyi ni awọn orilẹ-ède aiye nwá kiri: Baba nyin si mọ̀ pe, ẹnyin nfẹ nkan wọnyi.

Ka pipe ipin Luk 12

Wo Luk 12:30 ni o tọ