Luk 13:17 YCE

17 Nigbati o si wi nkan wọnyi, oju tì gbogbo awọn ọtá rẹ̀: gbogbo ijọ enia si yọ̀ fun ohun ogo gbogbo ti o ṣe lati ọwọ́ rẹ̀ wá.

Ka pipe ipin Luk 13

Wo Luk 13:17 ni o tọ