Luk 13:24 YCE

24 Ẹ làkaka lati wọ̀ oju-ọ̀na tõro: nitori mo wi fun nyin, enia pipọ ni yio wá ọ̀na ati wọ̀ ọ, nwọn kì yio si le wọle.

Ka pipe ipin Luk 13

Wo Luk 13:24 ni o tọ