Luk 14:23 YCE

23 Oluwa na si wi fun ọmọ-ọdọ na pe, Jade lọ si opópo, ati si ọ̀na ọgbà, ki o si rọ̀ wọn lati wọle wá, ki ile mi le kún.

Ka pipe ipin Luk 14

Wo Luk 14:23 ni o tọ