Luk 14:31 YCE

31 Tabi ọba wo ni nlọ ibá ọba miran jà, ti kì yio kọ́ joko, ki o si gbèro bi yio le fi ẹgbarun padegun ẹniti nmu ẹgbawa bọ̀ wá kò on loju?

Ka pipe ipin Luk 14

Wo Luk 14:31 ni o tọ