Luk 14:9 YCE

9 Nigbati ẹniti o pè ọ ati on ba de, a si wi fun ọ pe, Fun ọkunrin yi li àye; iwọ a si wa fi itiju mu ipò ẹhin.

Ka pipe ipin Luk 14

Wo Luk 14:9 ni o tọ