Luk 15:6 YCE

6 Nigbati o si de ile, o pè awọn ọrẹ́ ati aladugbo rẹ̀ jọ, o nwi fun wọn pe, Ẹ ba mi yọ̀; nitoriti mo ri agutan mi ti o ti nù.

Ka pipe ipin Luk 15

Wo Luk 15:6 ni o tọ