Luk 16:31 YCE

31 O si wi fun u pe, Bi nwọn kò ba gbọ́ ti Mose ati ti awọn woli, a kì yio yi wọn li ọkan pada bi ẹnikan tilẹ ti inu okú dide.

Ka pipe ipin Luk 16

Wo Luk 16:31 ni o tọ