Luk 16:8 YCE

8 Oluwa rẹ̀ si yìn alaiṣõtọ iriju na, nitoriti o fi ọgbọ́n ṣe e: awọn ọmọ aiye yi sá gbọ́n ni iran wọn jù awọn ọmọ imọlẹ lọ.

Ka pipe ipin Luk 16

Wo Luk 16:8 ni o tọ