19 O si wi fun u pe, Dide, ki o si mã lọ: igbagbọ́ rẹ mu ọ larada.
Ka pipe ipin Luk 17
Wo Luk 17:19 ni o tọ