Luk 17:29 YCE

29 Ṣugbọn li ọjọ na ti Loti jade kuro ni Sodomu, ojo ina ati sulfuru rọ̀ lati ọrun wá, o si run gbogbo wọn.

Ka pipe ipin Luk 17

Wo Luk 17:29 ni o tọ