Luk 17:37 YCE

37 Nwọn si da a lohùn, nwọn bi i pe, Nibo, Oluwa? O si wi fun wọn pe, Nibiti okú ba gbé wà, nibẹ̀ pẹlu ni idì ikojọ pọ̀ si.

Ka pipe ipin Luk 17

Wo Luk 17:37 ni o tọ