Luk 18:43 YCE

43 Lojukanna o si riran, o si ntọ̀ ọ lẹhin, o nyìn Ọlọrun logo: ati gbogbo enia nigbati nwọn ri i, nwọn fi iyìn fun Ọlọrun.

Ka pipe ipin Luk 18

Wo Luk 18:43 ni o tọ