Luk 19:43 YCE

43 Nitori ọjọ mbọ̀ fun ọ, ti awọn ọtá rẹ yio wà yàra ká ọ, nwọn o si yi ọ ká, nwọn o si ká ọ mọ́ niha gbogbo.

Ka pipe ipin Luk 19

Wo Luk 19:43 ni o tọ