Luk 20:27 YCE

27 Awọn Sadusi kan si tọ̀ ọ wá, awọn ti nwọn nwipe ajinde okú kò si: nwọn si bi i,

Ka pipe ipin Luk 20

Wo Luk 20:27 ni o tọ