Luk 20:6 YCE

6 Ṣugbọn bi awa ba si wipe, Lati ọdọ enia; gbogbo enia ni yio sọ wa li okuta; nitori nwọn gbagbọ pe, woli ni Johanu.

Ka pipe ipin Luk 20

Wo Luk 20:6 ni o tọ