Luk 21:23 YCE

23 Ṣugbọn egbé ni fun awọn ti o lóyun, ati awọn ti o nfi ọmú fun ọmọ mu ni ijọ wọnni! nitoriti ipọnju pipọ yio wà lori ati ibinu si awọn enia wọnyi.

Ka pipe ipin Luk 21

Wo Luk 21:23 ni o tọ