Luk 21:28 YCE

28 Ṣugbọn nigbati nkan wọnyi ba bẹ̀rẹ si iṣẹ, njẹ ki ẹ wò òke, ki ẹ si gbé ori nyin soke; nitori idande nyin kù si dẹ̀dẹ.

Ka pipe ipin Luk 21

Wo Luk 21:28 ni o tọ